Oṣù Bíbélì Àgbáyé
Yorùbá

Tẹ̀ẹ́

Ohun gbogbo tí o níílò láti pín ìtàn Bíbélì.

Ní oṣù kọkànlá yìí, àwọn ènìyàn, iṣẹ́ ìránṣẹ́, ilé iṣẹ́ àgbáyé àti àwọn áàpù Bíbélì ń kó ara jọ láti ṣe àtìlẹ́yìn fún Oṣù Bíbélì Àgbáyé.

Àwọn Èròjà Ìròyìn

Àwọn àwòrán

Àwọn àmì ìdánimọ̀ Oṣù Bíbélì Àgbáyé, àwọn àwòrán ìpolongo, àti àwọn mìíràn.

Fọ́tòyíyà

Àwọn fọ́tò àwọn ènìyàn tí ń ka Bíbélì nínú ìgbésí ayé ojoojúmọ́, àti àwọn ìpolongo ìpolówó ọjà ńláńlá.

Ìwé òkodoro-ọ̀rọ̀

Àwọn òkodoro pàtàkì àti àlàyé nípa Oṣù Bíbélì Àgbáyé.

Ṣé ò n ṣiṣẹ́ l'órí ìtàn kan?

Sọ fún wa ohun tí o ń ṣiṣẹ́ lé lórí àti bí a ṣe lè ràn ọ́ lọ́wọ́. Ẹgbẹ́ wa ń retí láti bá ọ sọ̀rọ̀!

Àwọn Alábàáṣiṣẹ́pọ̀ Oṣù Bìbélì ní Àgbáyé